Ikedi Godson Ohakim (ojoibi 4 August, 1957) je oloselu omo ile Naijiria ati Gomina Ipinle Imo lati 2007 titi de 2011.
Itokasi
|
---|
Ìpínlẹ̀ Imo ni wọ́n dá sílẹ̀ ní ọjọ́ Kẹtàdínlógún oṣù kẹta ọdún 1976, àwọn Àtòjọ àwọn Gómìnà Gómìnà tí wọ́n ti ja ní Ìpínlẹ̀ naa:
|