Evan Enwerem (October 29, 1935 - August 2, 2007) je oloselu omo ile Naijiria to je ipo Aare ile Alagba Naijiria ni 1999.[1]
O je omo egbe oloselu People's Democratic Party.
Itokasi
|
---|
Ìpínlẹ̀ Imo ni wọ́n dá sílẹ̀ ní ọjọ́ Kẹtàdínlógún oṣù kẹta ọdún 1976, àwọn Àtòjọ àwọn Gómìnà Gómìnà tí wọ́n ti ja ní Ìpínlẹ̀ naa:
|