Amadi Guy Ikwechegh (25 February 1951 - 10 November 2009) je omo ologun oju-omi orile-ede Naijiria to je yiyan si ipo Gomina Ipinle Imo lati 1986 de 1989 nigba ijoba ologun Ogagun Ibrahim Babangida.[1]
Itokasi
|
---|
Ìpínlẹ̀ Imo ni wọ́n dá sílẹ̀ ní ọjọ́ Kẹtàdínlógún oṣù kẹta ọdún 1976, àwọn Àtòjọ àwọn Gómìnà Gómìnà tí wọ́n ti ja ní Ìpínlẹ̀ naa:
|