Gómìnà jẹ́ ẹni tí a fi ìbò yàn sí orí ipò adarí ìlú tàbí Ìpínlẹ̀ kan lábẹ́ àṣẹ orílẹ̀-èdè tí ó rọ̀ mọ́ ìsèlú. Èyí dá lórí irúfẹ́ orílẹ̀-èdè àti irúfẹ́ ìsèlú tí Won báà ṣe àmúlò rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè náà.[1] Ó ṣe é ṣe kí wọ́n fìbò yan gómìnà, bákan náà ni wọ́n lè yànán láì lo ìbò rárá. Agbára tí ó wà lọ́wọ́ àwọn gómìnà ma ń ju ara wọn lọ gẹ́gẹ́ bí òfin orílẹ̀-èdè tí wọ́n ti ń ṣe aláṣẹ bá dálé lórí.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ "GOVERNOR Definition & Meaning". Dictionary.com. 2020-09-16. Retrieved 2024-04-19.
- ↑ "Penguin Random House". PenguinRandomhouse.com. Archived from the original on 2006-08-27. Retrieved 2009-03-13.