Ike Omar Sanda Nwachukwu (ojoibi September 1, 1940)[1] jẹ́ ọmọ ológun tótifèyìntì àti olósèlú ará ilè Nàìjíríà tó di ọ̀pọ̀lọpọ̀ ipò mú ní ìjọba Nàìjírí̀a, ó di Alákòso Ọrọ òkèrè lẹ́ẹ̀mejì̀, Gómínà Ìpínlè Ímò àti Alágba nínú àwọn asojú Ilè-ìgbìmọ̀ Asòfin lati Ìpínlè Ábíá.
Ìtókasí
|
---|
Ìpínlẹ̀ Imo ni wọ́n dá sílẹ̀ ní ọjọ́ Kẹtàdínlógún oṣù kẹta ọdún 1976, àwọn Àtòjọ àwọn Gómìnà Gómìnà tí wọ́n ti ja ní Ìpínlẹ̀ naa:
|