Joy Uche Angela Ogwu (tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1946) jẹ́ mínísítà Nàìjíríà tẹ́lẹ̀rí àti asojú Nàìjíríà sí ẹgbẹ́ United Nations ní New York láàrin ọdún 2008 sí 2017.[1][2] Òun ni obìnrin àkọ́kọ́ láti jẹ́ asojú sí egbẹ́ United Nations làti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[3] Kí ó tó di mínísítà, Ogwu, tí ó jẹ́ ọmọ Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà, jẹ́ adarí àgbà Nigerian Institute of International Affairs (NIIA).[4]
Ààrẹ Olusegun Obasanjo yàn gẹ́gẹ́ bi òkè òkun ní ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹjọ ọdún 2006.[5]
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ "Home" (in en-US). Permanent Mission of Nigeria to the United Nations, New York. http://www.nigeriaunmission.org/.
- ↑ "New Permanent Representative of Nigeria Presents Credentials" (in en-US). https://www.un.org/press/en/2017/bio4963.doc.htm.
- ↑ "Joy Ogwu | Ambassador Series Lecture". events.adelphi.edu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-25.
- ↑ III, Editorial (2019-04-27). "Joy Ogwu, Bolaji Akinyemi: Where are they now?" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-25.
- ↑ "Joy Ogwu: Quintessential Diplomat". The Pointer News Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2014-07-19. Retrieved 2020-05-25.