A bí i ní 18th January, 1932 ní ìpínlẹ̀ Anambra ní ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó lọ sí ile-ẹ̀kọ́ ní Merchant of Light School, Oba; University of Ibadan, Institute of Public Administration, London; Cavillam Institute, France. Ó ti ṣe minister of foreign affairs rí. Ó ṣiṣẹ́ ní Foreign Service. Ó jẹ Secretary Commonwealth.