Adams Aliyu Oshiomhole |
---|
Adams Oshiomhole, former President of the Nigeria Labour Congress (right) with U.S. Ambassador to Nigeria Howard F. Jeter (center), 5 July 2002, Lagos. |
|
National Chairman of the All Progressives Congress |
---|
Lọ́wọ́lọ́wọ́ |
Ó gun orí àga 24 July 2018 |
Governor of Edo State |
---|
In office 12 November 2008 – 12 November 2016 |
Asíwájú | Oserheimen Osunbor |
---|
Arọ́pò | Godwin Obaseki |
---|
|
Adams Oshiomhole (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrin oṣù kẹrin ọdún 1952) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèlú ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ẹ̀dó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni Alága ẹgbẹ́ òṣèlú-ṣèjọba tí All Progressives Congress(APC).[1] Oshiomhole ti fìgbà kan jẹ́ Gómìnà ìpínlẹ̀ Ẹ̀dó láti ọdún 2008 sí ọdún 2016 lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú Action Congress of Nigeria.[2] Kí ó tó di àkókò yìí, òun ni Alága ẹgbẹ́ àwọn òṣìṣẹ́, NLC lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà nígbà ìṣèjọba Ààrẹ àná, Olúṣẹ́gun Ọbásanjọ́.[3]
Àwọn Ìtọ́kasí