Emmanuel Eweta Uduaghan (ojoibi 22 October 1954) ni Gomina Ipinle Delta lowolowo ni Nigeria lati May 29 2007, o je omo egbe oloselu People's Democratic Party (PDP). Ki o to di Gomina o je Asakoso fun Ilera ni Ipinle Delta ati Akowe fun Ijoba Ipinle Delta.[1]
Itokasi