Godwin Nogheghase Obaseki (Ọjọ́ ìbí: 1 Agẹmọ, 1957, ní Ilu Benin, Nigeria [1] ) jẹ́ olóṣèlú àti oníṣòwò kan ní ìlú Naijiria to sì jẹ Gómìnà Ipinle Edo àtọwò. Wọ́n gbé ìpò gómíná fun ní ọjó ìkejìla, Bèlu, 2016 ní. Oun lo jẹ́ Olóyè Edo State Economic and Strategy Team látọwọ́ gómìnà ìṣáájú, Adams Oshiomole, ní òṣù Erẹ́nà, l ọdún 2009.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2019-12-26. Retrieved 2019-12-13.