Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà |
---|
|
Type |
---|
Type | |
---|
Leadership |
---|
| |
---|
| |
---|
Seats | 109 |
---|
Meeting place |
---|
|
Abuja |
Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin Àgbà Orílẹ̀ Èdè Nàìjíríà jẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin gíga ti ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin oníbínibí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. O ní àwọn asò̀fin 109: ìkọ̀ọ̀kan àwọn ìpínlẹ̀ mẹ́r̀ndínlógójì jẹ́ pípín sí agbèègbè asòfin mẹta tí wón dìbòyàn asòfin kọ̀ọ̀kan; bé̀ẹ̀ sì ni agbè̀gbè olúìlú ìjọba àpapọ̀ náà dìbòyàn asòfin kan pééré.
Awon Arannise Ipinle Naijiria
Àwọn Alàgbà
Àwọn ìtọ́kasí
Àdàkọ:Oselu ni Naijiria