George Akume |
---|
|
Gómìnà Ìpínlẹ̀ Benue |
---|
In office Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 1999 – Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 2007 |
Asíwájú | Dominic Oneya |
---|
Arọ́pò | Gabriel Suswam |
---|
Ààrẹ Ilé-ìgbìmọ̀ Aṣòfin Nàìjíríà |
---|
Lọ́wọ́lọ́wọ́ |
Ó gun orí àga Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 2007 |
|
Àwọn àlàyé onítòhún |
---|
Ọjọ́ìbí | 27 Oṣù Kejìlá 1953 (1953-12-27) (ọmọ ọdún 71) |
---|
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress (APC) |
---|
George Akume (bíI Ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀ Oṣù kejìlá Ọdún 1953) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ̀ Benue tẹ́lẹ̀. Òhun ni ààrẹ Ile-igbimo Asofin Naijiria tí ó sì jẹ́ aṣojú fún abasoju Àríwá-ìwòorùn Benue láti Ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 2007.
[1]
Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin lẹ́yìn tí ó wọlé látàrí ètò ìdìbò ti oṣù kẹrin ọdún 2007 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú Action Congress of Nigeria.
Àwọn ìtọ́kasí