Philips Tanimu Aduda jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú Abuja, ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà.[1] Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2011 sí Ọdún 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[2]
Àwọn ìtọ́kasí