Mohammed Namadi Sambo (ojoibi August 2, 1954) je oloselu omo orile-ede Naijiria ati Igbákejì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà tele fun ijoba Aare Goodluck Jonathan. O tun ti je Gomina Ipinle Kaduna lati 2007 titi de 2010.
Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.
Strategi Solo vs Squad di Free Fire: Cara Menang Mudah!