Coordinates: 29°34′24″N 2°22′23″E / 29.5734571°N 2.3730469°E / 29.5734571; 2.3730469
Àlgéríà (Arabiki: الجزائر, al-Gazā’ir), fun onibise Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú àwọn Ènìyàn ilẹ̀ Àlgéríà, je orile-ede ni Àríwá Áfríkà. Ile re ni ti orile-ede ti o tobijulo ni Okun Mediterraneani, ekeji totobijulo ni orile Áfríkà[10] leyin Sudan, ati ikokanla totobijulo lagbaye.[11]
Àlgéríà i bode ni ariwailaorun mo pelu Tùnísíà, ni ilaorun pelu Libya, ni iwoorun pelu Moroko, ni guusuiwoorun pelu Apaiwoorun Sahara, Mauritania, ati Mali, ni guusuilaorun pelu Niger, ati ni ariwa pelu Okun Mediterraneani Sea. Titobi re fe je 2,400,000 square kilometres (930,000 sq mi), be si ni iye awon eniyan re je 35,700,000 ni January 2010.[12] The capital of Algeria is Algiers.
Àlgéríà je omo egbe Iparapo awon Orile-ede, Isokan Afrika, ati OPEC. Bakanna o tun kopa ninu dida ikoenu owo Isokan Maghreb.
Akiyesi
Itokasi
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/>
tag was found