Màláwì ( /məˈlɑːwi/; Chichewa Àdàkọ:IPA-ny), lonibise bi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Màláwì, je orílẹ̀-èdè àdèmọ́àrinlẹ̀ kan ni guusuilaorun Afrika to je mi mo tele bi Ilẹ̀ Nyasa. O ni bode mo Zambia ni ariwaiwoorun, Tanzania ni ariwailaorun, ati Mozambique ni ilaorun, guusu ati iwoorun. Orile-ede na je pinpinniya si Tanzania ati Mozambique pelu Omi-adagun Malawi. Malawi tobi to 118,000 km2 (45,560 sq mi) pelu awon alabugbe ti idiye won ju 13,900,000 lo. Oluilu re ni Lilongwe, to tun je ilu totobijulo ni be; ikeji totobijulo ni Blantyre ati iketa ni Mzuzu. Malawi bi oruko re wa lati Maravi, oruko atijo fun awon Nyanja ti won budo si be. Won tun unpe orile-ede yi bi "Ọkàn Alọ́wọ́rọ́ Afrika".[8]
Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.
<ref>
Flag
Benson1