Uyo ni olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ní Guusu Nàìjíríà. Ibibio ni èdè tí wón sọ ní ìlú Uyo.[1][2] Uyo di olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ní ọjọ́ ketalelogun oṣù kẹsàn(Sept 23), ọdún 1987 nígbà tí Akwa Ibom yapa kúrò lára Ìpínlẹ̀ Cross River. Gẹ́gẹ́ bi àbájáde ètò ìkànìyàn Nàìjíríà ọdún 2006, iye àwọn ènìyàn tí ó ń gbé Uyo (àti ní ìlú Itu) jẹ́ 427,873.[3]
5°03′N 7°56′E / 5.050°N 7.933°E / 5.050; 7.933
Àwọn olúìlú ìpínlẹ̀ Nàìjíríà |
---|
|
Àwọn Ìtókasí
- ↑ "Uyo | Location, Facts, & Population". Encyclopedia Britannica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-12.
- ↑ "Uyo | Location, Facts, & Population | Britannica". www.britannica.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-11-14.
- ↑ Summing the 2 LGAs Uyo and Itu LGA's as per:
Federal Republic of Nigeria Official Gazette (15 May 2007). "Legal Notice on Publication of the Details of the Breakdown of the National and State Provisional Totals 2006 Census" (PDF). Archived from the original (PDF) on 2012-03-05. Retrieved 2007-05-19.