Jalingo ni olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Taraba ní ariwa ìwọ oòrùn Nàìjíríà , Jalingo ní èdè fulfulde túmọ̀ sí "ibi gíga", ó sì ní olùgbé 418,000. Àwọn Fulani àti àwọn ẹ̀yà kẹ́kẹ̀ kẹ́ mìíràn ni ó wà ní ìlú Jalingo.[1] Fulfulde, Mumuye, Hausa àti àwọn èdè míràn ni wọ́n ń sọ ní Jalin
Alámòjútó Alága
Ìjọba ìbílè kọ̀ọ̀kan ní Nàìjíríà lóní alámòjútó alága tó ń darí wọn. Àwọn ni wọ́n ń darí ètò ìpílẹ̀.
Alága tí wọ́n yàn ní Jalingo ní ètò ìdìbò 2020 tó kọjá[2] ni Hon. Abdulnaseer Bobboji ti ẹgbẹ́ òṣẹ̀lú People Democratic Party (PDP).[3] Ó ti jẹ́ alámòjútó alága títí tó fi parí àsìkò rẹ̀ ní ọjọ́ Àìkú, oṣù kéje, ọdún 2022.[4][5] gómínà ipínlẹ̀ Taraba Arch. Darius Dickson Ishaku yan aṣojú ètò-ìlera Primary Health Care Development Agency Alh. Aminu Jauro gẹ́gẹ́ bí alámòjútó alága tí Jalingo.[6][7]
Ọjà
Jalingo jẹ́ olú-ìlú ìpínlẹ̀ Taraba ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọjà ṣùgbọ́n àwọn ọjà tó gbajúmọ̀ jù.
- Jalingo Main Market[8]
- Kasuwan Yelwa (Yelwa Market)[9]
Àwọn Ìtọ́kasí
Àwọn olúìlú ìpínlẹ̀ Nàìjíríà |
---|
|