Owerri ( /oʊˈwɛri/ oh-WERR-ee,[1] Igbo: Owèrrè)[2] ni olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Imo ní Nàìjíríà, ìlú náà wà láàrin ilẹ̀ igbó.[3] Òun tún ni ìlú tí ó tóbi jù ní Ìpínlẹ̀ Imo, ìlú Orlu, Okigwe àti Ohaji/Egbema sì ni ó tẹ̀lẹ́. Owerri ní ìjọba ìbílè mẹta, àwọn ni Owerri Municipal, Owerri North àti Owerri West, ìlú Owerri ní àwọn olùgbé 1,401,873 ní ọdun 2016. Owerri pín àlà pẹ̀lú Otamiri River ní apá ìwọ̀ oòrùn rẹ̀ àti Nworie River ní apá gúúsù rẹ̀.[4]
Àwọn Ìtọ́kasí
Àwọn olúìlú ìpínlẹ̀ Nàìjíríà |
---|
|