Makurdi ni olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Benue, tí ó wà ní àárín Nàìjíríà,[1] Ìlú náà wà ní apá gúúsù Benue River. Ní ọdún 2016, àwọn olùgbé Makurdi àti agbègbè rè jẹ́.[2][3][4]
Ìtàn
Wọ́n tèdó ìlú Makurdi ní ọdun 1927. Ní ọdún 1976, Makurdi di olú-ìlú ìpínlè Benue.
Àwọn olúìlú ìpínlẹ̀ Nàìjíríà |
---|
|
Àwọn Ìtókasí
- ↑ "Makurdi | Encyclopedia.com". www.encyclopedia.com. Retrieved 2021-06-10.
- ↑ "Makurdi | Location, Facts, & Population". Encyclopedia Britannica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-26.
- ↑ "Government of Benue State". Government of Benue State (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-26.
- ↑ "The World Gazetteer". Archived from the original on 9 February 2013. Retrieved 6 April 2007.