Pierre Curie (15 May 1859 – 19 April 1906) je omo orile-ede Fransi to je onimo fisiyiki, asiwaju ninu kristalografi, isegberingberin, piezoelectricity ati radiolilagabra, ati elebun Nobel. Ni 1903 o gba Ebun Nobel ninu Fisiyiki pelu iyawo re, Maria Skłodowska-Curie, ati Henri Becquerel, "fun idamo ise pataki ti won se nipa iwadi papo won lori isele itankakiri ti Ojogbon Henri Becquerel se awari."
Itokasi
|
---|
Non SI unit | |
---|
SI unit | |
---|
Physical constant | |
---|