Marie Salomea Skłodowska-Curie (Ojo keje, osu kankanla, odun 1867 – Ojo Kerin, osu keje, odun 1934) je onimo fisiyiki ati onimo kemistri omo orile-ede Poland to di ara Fransi lojowaju. O je asiwaju ninu papa radiolilagbara ati eni akoko to gba Ebun Nobel meji[1] — ninu fisiyiki ati kemistri. Ohun na lo tun je obinrin akoko to je ojogbon ni Yunifasiti ilu Paris.
Itokasi
|
---|
1901–1925 | |
---|
1926–1950 | |
---|
1951–1975 | |
---|
1976–2000 | |
---|
2001–dòní | |
---|
|
|
---|
Non SI unit | |
---|
SI unit | |
---|
Physical constant | |
---|