Sir William Lawrence Bragg CH OBE MC FRS[1] (31 March 1890 – 1 July 1971) ni o kere ju ninu awon eni ti o ti gba Nobel Prize titi di odun 2001. Omo Australia ara Britani ni. Omo odun marundinlogbon ni o je nigba ti o gba Nobel Prize ninu fisiksi ni odun 1915.
Itokasi