Johann Carl Friedrich Gauss (pípè /ˈɡaʊs/; listen (ìrànwọ́·ìkéde), Látìnì: Carolus Fridericus Gauss) (30 April 1777 – 23 February 1855) je ara Germany onimo-mathematiki ati onimosayensi ti o ko ipa to se koko ninu opo omo ijinle, bi iro nomba, statistiki, ituyewo mathematiki, Jeometria oniyato, geodesy, geophysics, electrostatics, itorawo ati iriran. Won pe ni Princeps mathematicorum[1] (Latini, fun "Arole awon Onimo-mathematiki" tabi "asiwaju awon onimo-mathematiki") ati "onimo-mathematiki olokikijulo lati atijo", Gauss ko ipa gidigidi ninu opo papa imo mathematiki ati sayensi.[2] He referred to mathematics as "the queen of sciences."[3]
Itokasi
- ↑ Zeidler, Eberhard (2004). Oxford User's Guide to Mathematics. Oxford, UK: Oxford University Press. p. 1188. ISBN 0198507631.
- ↑ Dunnington, G. Waldo. (May, 1927). "The Sesquicentennial of the Birth of Gauss". Scientific Monthly XXIV: 402–414. Retrieved on 29 June 2005. Comprehensive biographical article.
- ↑ Smith, S. A., et al. 2001. Algebra 1: California Edition. Prentice Hall, New Jersey. ISBN 0-13-044263-1
|
---|
Non SI unit | |
---|
SI unit | |
---|
Physical constant | |
---|