Ìpínlẹ̀ Òndó
Ìtàn ṣókí nípa Ondon láti ẹnu ọmọ bíbí ìlú Ondo.
Ìpínlẹ̀ Ondo jẹ́ ìpínlẹ̀ kan ní gúúsù-ìwọ̀oòrùn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà . wọ́n da sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹ́ta oṣù kejí ọdún 1976 látara àwọn Ìpínlẹ̀ Ìwọ̀ Oòrùn tẹ́lẹ̀ rí.[ 4] Ìpínlẹ̀ Ondo pín ààlà pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ Ekiti sí àríwá , pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ Kogi sí àríwá-ìlà-oòrùn, pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ Edo sí ìlà-oòrùn, pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ Delta sí gúúsù-ìlà-oòrùn, pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ Ogun sí gúúsù-ìwọ̀ oòrùn, pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ Osun sí àríwá-ìwọ̀ oòrùn, àti pẹ̀lú Atlantic Ocean sí gúúsù.[ 5] Tí olú ìlú rẹ̀ jẹ́ Akure , ìyẹn olú-ìlu ẹkùn-ìjọba Akure àtijọ .[ 6] Ìpínlẹ̀ Ondo ni igbó mangrove-swamp wà lẹ́ba àwọn ìgbèríko ìlu Benin .[ 7]
Creek in southern Ondo state
Tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ njẹ́ "Sunshine State", Ìpínlẹ̀ Ondo jé ọ̀kàndìnlógún Ìpínlẹ̀ tí ó pọ̀ jùlọ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà ,[ 8] tí ó sì jẹ́ ìpínlẹ̀ karùndínlọ́gbọ̀n tó fẹ̀ jùlọ gẹ́gẹ́ bí ìwọ̀n ilẹ̀ gbígbà.[ 9] Yoruba ni ó gbilẹ̀ jùlọ ní ìpínlẹ̀ náà,[ 10] [ 11] èdè Yorùbá ni wọn ń sọ jù níbẹ̀.[ 12] Ilé-iṣẹ́ epo-bẹntiróò ni ó gbilẹ̀ jù gẹ́gẹ́ bí ètò ọrọ̀-ajé ní ìpínlẹ̀ náà. òwo Cocoa , wíwa asphalt , àti àwọn ọ̀gọ̀rọ̀ iṣẹ́ etí òkun pẹ̀lú èto ọrọ̀-ajé ìpínlẹ̀ náà.[ 13] Ilé àwọn òkè Idanre ni, tí ó kó ipa tó ga jùlọ nínú ìdajì àwọn agbègbè ìwọ̀-oòrùn tí ó làmìlaka lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó ga ju ìwọn ọgọ́run mítà lọ ní títayọ.
Ìjọba àti àwùjọ
Ìpínlẹ̀ náà ṣàkóónu ẹkùn ìjọba ìbílẹ̀ méjìdínlógún , àwọn tí ó jẹ́ gbòógì náà nìwọ̀nyí Akoko , Akure , Okitipupa , Ondo , Ilaje , Idanre àti Owo . Púpọ̀ nínú àwọn ará ìpínlẹ̀ náà ń gbé ní àwọn ilu tí ó lajú. Àwọn fáfitì ìjọba tí ó gbajúgbajà ní ìpínlẹ̀ Ondo náà nìwọ̀nyí Federal University of Technology Akure , Akure Ondo State University of Science and Technology , Okitipupa University of Medical Sciences, Ondo , Ondo àti Adekunle Ajasin University , Akungba Akoko .[ 14]
Àwọn ẹkùn ìjọba ìbílẹ̀
Ìpínlẹ̀ Ondo ṣàkóónu ẹkùn ìjọba ìbílẹ̀ méjìdínlógún , wọn sì ni:
Gómìnà
Akeredolu Oluwarotimi Odunayo [ 16] jẹ́ gómìnà lọ́ọ́lọ́ọ́ ti Ìpínlẹ̀ Ondo.[ 17] Gómìnà Oluwarotimi Odunayo Akeredolu ti ẹgbẹ oṣelu "All Progressives Congress" (APC) ni wọ́n ṣe ìbúra fún bọ́sípò ní ọjọ́ kẹrìnlélógún oṣù kejì, ọdún 2017 jẹ lẹ́yìn Olusegun Mimiko .[ 18] Lucky Aiyedatiwa ni igbákejì gómìnà ìpínlẹ̀ Ondo.[ 19]
Àwọn ọ̀wọ́ ẹ̀yà
Ọ̀wọ́ ẹ̀yà ní ìpínlẹ̀ Ondo kún fún ọ̀pọ̀ ẹ̀yà Yoruba ìdá ọ̀wọ́ ti Idanre , Akoko , Akure , Ikale , Ilaje , Ondo, àti àwọn èèyàn Owo . Ará Ijaw , bẹ́ẹ̀ náà ni ọ̀gọ̀rọ̀ àwọn Apoi àti Arogbo ń gbé ní gúúsù-ìlà-oòrùn létí omi tó súnmọ́ ààlà ìpínlẹ̀ Edo. Díẹ̀ nínú àwọn èrò tí wọ́n ń sọ ẹ̀ka èdè Yorùbá tí ó jọ èdè Ife ní Oke-Igbo tí ó súnmọ́ ààlà ìpínlẹ̀ Osun.[ 20] Ọ̀gọ̀rọ̀ àwọn èrò yìí jẹ́ ẹlẹ́siǹ Kììtẹ́nì; tí àwọn diẹ jẹ́ ẹlẹ́siǹ Mùsùlùmí àti àbàlàyé.[ 21] [ 22]
Àwọn èdè
Àtòpọ̀ àwọn èdè ní ìpínlẹ̀ Ondo látọwọ́ àwọn ẹkùn ìjọba ìbílẹ̀:[ 23]
LGA
Languages
Akoko South East
Yoruba (Ao), Uhuami , Ukue
Akoko South West
Yoruba (Akoko, Ekiti )
Akoko North East
Yoruba (Akoko), Arigidi , Ayere
Akoko North West
Yoruba (Akoko, Ekiti), Abesabesi , Arigidi, Ayere
Akure North
Yoruba (Ekiti)
Akure South
Yoruba (Ekiti)
Ese-Odo
Yoruba (Apoi), Izon
Idanre
Yoruba (Ondo, Ekiti)
Ifedore
Yoruba (Ekiti)
Ilaje
Yoruba (Ilaje)
Ile Oluji/Okeigbo
Yoruba (Ondo, Ife)
Irele
Yoruba (Ikale)
Odigbo
Yoruba (Ikale, Ondo)
Okitipupa
Yoruba (Ikale)
Ondo East
Yoruba (Ondo)
Ondo West
Yoruba (Ondo)
Ose
Yoruba (Ogho, Ao), Owan (Ora )
Owo
Yoruba (Ogho)
Àwọn ohun àlùmọ́nì ní ìpínlẹ̀ Ondo
Àwọn ohun wọ̀nyí ni ohun àlùmọ́nì ti wọ́n ní ìpínlẹ̀ Ondo:[ 24]
Bitumen
Coal
Dimension stones
Feldspar
Gemstones
Glass/and
Granite
Gypsum
Kaolin
Limestone & oil/gas
Àwọn ilé-ẹ̀kọ́ gíga
Àtẹ́ dẹ̀mógíráfì
Ètò ìpín-kíka àwọn ènìyàn ní ìpínlẹ̀ Ondo[ 37]
Local government area
Male
Female
Total
Akoko North-West
108,057
105,735
213,792
Akoko North-East
93,060
82,349
175,409
Akoko South-East
41,995
40,431
82,426
Akoko South-West
123,979
105,507
229,486
Ose
73,395
71,506
144,901
Owo
110,429
108,457
218,886
Akure North
66,878
64,709
131,587
Akure South
175,495
177,716
353,211
Ifedore
92,014
84,313
176,327
Ile Oluji
87,505
85,365
172,870
Ondo West
139,400
144,272
283,672
Ondo East
38,032
36,726
74,758
Idanre
66,996
62,028
129,024
Odigbo
114,814
115,537
230,351
Okitipupa
120,626
112,939
233,565
Irele
75,636
69,530
145,166
Ese Odo
78,100
76,878
154,978
Ilaje
154,852
135,763
290,615
Total
1,761,263
1,679,761
3,441,024
Àwọn èèyàn Jànkànjànkàn
Mo Abudu – media mogul[ 38]
Gani Adams – activist and politician[ 39]
Kayode Ajulo - Lawyer[ 40]
King Sunny Adé – musician[ 41]
Michael Ade-Ojo – business magnate[ 42]
Adebayo Adefarati – former Governor Ondo State[ 43]
Rotimi Adelola – former Secretary to the State Government[ 44]
Tayo Adenaike – painter[ 45]
Ilesanmi Adesida – physicist[ 46]
Akintunde Aduwo – former Governor Western Region/Navy Vice[ 47]
Olusegun Agagu – former Governor Ondo state[ 48]
Michael Adekunle Ajasin – Politician, Former governor of Ondo State [citation needed ]
Rotimi Akeredolu – politician[ 49]
Abayomi Akinruntan , politician[citation needed ]
Akintunde Akinwande – engineering professor[ 50]
Yemi Alade – musician[ 51]
Funmi Aragbaye – gospel singer[ 52]
Bamidele Aturu – human rights activist[ 53]
Akinyelure Patrick Ayo – banker, politician[ 54]
Reekado Banks – singer, songwriter[ 55]
Robert Ajayi Boroffice – politician[ 56]
Hosea Ehinlanwo – former Senator[ 57]
Omotola Jalade Ekeinde – actress, singer[ 58]
Chinko Ekun – singer, rapper[ 59]
Olu Falae – banker, politician[ 60]
Frederick Fasehun – medical doctor, activist and politician[ 61]
Anthonia Fatunsin , Nigerian archeologist
Gani Fawehinmi – author, lawyer[ 62]
Jimoh Ibrahim – lawyer, politician[ 63]
T. B. Joshua – pastor, philanthropist[ 64]
Adetokunbo Kayode – lawyer and politician[ 65]
Boluwaji Kunlere – former Senator[ 66]
Ayo Makun (AY Show) – comedian, Entertainer[ 67]
Nahzeem Olufemi Mimiko – educational administrator[citation needed ]
Olusegun Mimiko – former Governor Ondo State[ 68]
Bode Olajumoke – politician[ 69]
Chris Olukolade – army general[ 70]
Sola Sobowale – actress, director[ 71]
Omoyele Sowore – human rights activist[ 72]
Adekunle Temitope (a.k.a. Small Doctor) – musical artist[ 73]
Akinloye Tofowomo , performing musician
Waje – Musical Artist[ 74]
Àwọn Ilé-iṣẹ́ agbóhùn sáfẹ́fẹ́ àti amóhùn-máwòrán ní ìpínlẹ̀ Ondo
Àwọn àwòrán
Welcome to Etiaro, Akoko signpost
Welcome to Alayere town, Akure, Ondo state2.jpg
The Apostolic High School, Ilara-Mokin
St James Catholic Church, Ugbe-Afo, Ondo state3.jpg
St James Catholic Church, Ugbe-Afo, Ondo state.jpg
References
↑ "2006 PHC Priority Tables – NATIONAL POPULATION COMMISSION" . population.gov.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2017-10-10. Retrieved 2017-10-10 .
↑ 2.0 2.1 "C-GIDD (Canback Global Income Distribution Database)" . Canback Dangel. Retrieved 2010-08-20 .
↑ "Sub-national HDI – Area Database – Global Data Lab" . hdi.globaldatalab.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-09-13 .
↑ "Ondo Election: 20 things to know about South-west state" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-10-09. Retrieved 2022-04-08 .
↑ "Ondo | state, Nigeria" . Encyclopedia Britannica .
↑ "Ondo | state, Nigeria" . Encyclopedia Britannica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-23 .
↑ "Ondo | state, Nigeria" (in en). Encyclopedia Britannica . https://www.britannica.com/place/Ondo-state-Nigeria .
↑ (PDF) https://web.archive.org/web/20110519235026/http://www.population.gov.ng/files/nationafinal.pdf . Archived from the original (PDF) on 19 May 2011. Retrieved 2022-04-19 .
↑ "World Gazetteer: Nigeria - administrative divisions (per geographical…" . archive.ph . 2013-01-05. Archived from the original on 2013-01-05. Retrieved 2022-04-19 .
↑ "The People Of Ondo Kingdom And Their Culture: A Historical Survey And Political Underpinning – Ondo Connects New Era" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-03-07 .
↑ "Geography and Society" , The Yoruba from Prehistory to the Present (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì), Cambridge University Press, pp. 1–28, 2019-07-04, ISBN 978-1-107-58765-6 , doi :10.1017/9781107587656.001 , retrieved 2021-03-07
↑ "Yoruba Online" . www.africa.uga.edu . Archived from the original on 2021-09-18. Retrieved 2021-03-07 .
↑ "Ondo State" . Nigerian Investment Promotion Commission (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-01-09. Retrieved 2021-03-07 .
↑ "Ondo State Trip Planner • Plan your Ondo State vacation itinerary" . Inspirock (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-04-15. Retrieved 2020-05-25 .
↑ "Ondo | Nigeria" . Encyclopedia Britannica .
↑ "Ondo State Government" . www.ondostate.gov.ng . Archived from the original on 2021-06-15. Retrieved 2022-09-11 .
↑ "Ondo state Governor" .
↑ Jannah, Chijioke (2017-02-24). "PHOTONEWS: Inauguration of Rotimi Akeredolu as Ondo governor" . Daily Post Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-18 .
↑ TODAY (2021-04-08). "2023: Ondo will go the direction of Governor Akeredolu – deputy" . TODAY (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-18 .
↑ Anderson, Liam D. (2013). Federal Solutions to Ethnic Problems: Accommodating Diversity . ISBN 9780415781619 . https://books.google.com/books?id=BiAEvKgVOmAC&q=The+ethnicity+of+Ondo+State&pg=PA149 . Retrieved June 19, 2015 .
↑ "Traditionalists, Christians clash in Ondo" . The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-07-16. Archived from the original on 2023-12-14. Retrieved 2022-04-13 .
↑ "Origin Of Islamic Religion In Ondo Kingdom – Ondo Connects New Era" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-13 .
↑ "Nigeria" . Ethnologue . https://www.ethnologue.com/country/NG .
↑ "Natural Resources – Welcome To The Embassy of Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-16 .
↑ "Adekunle Ajasin University – …21st Century University, properly called!" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-05-11. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Achievers University" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Adeyemi College of Education – Foremost Teachers Training Institute" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Home | Elizade University" . www.elizadeuniversity.edu.ng . Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Home" . Federal College of Agriculture (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28 .
↑ "FEDERAL POLYTECHNIC, ILE-OLUJI" . www.fedpolel.edu.ng . Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Home | The Federal University of Technology Akure" . www.futa.edu.ng . Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Akure Study Centre | National Open University of Nigeria" . nou.edu.ng . Archived from the original on 2021-06-28. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "OAUSTECH | OLUSEGUN AGAGU UNIVERSITY OF SCIENCE & TECHNOLOGY" . www.osustech.edu.ng . Archived from the original on 2021-06-24. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "RUFUS GIWA POLYTECHNIC | Advancement Through Technology" . www.rugipo.edu.ng . Archived from the original on 2021-06-28. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "University of Medical Sciences, Ondo" . www.unimed.edu.ng . Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Wesley University Ondo – Cream Of Wesleyans" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-06-12. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "National Population Commission of Nigeria" . population.gov.ng.
↑ Michelle Cohan and Nosmot Gbadamosi (29 March 2017). "The Nigerian Media mogul with a global empire" . CNN . Retrieved 2021-06-28 .
↑ "No going back on di call for Yoruba Nation – Gani Adams" . BBC News Pidgin . https://www.bbc.com/pidgin/tori-56605893 .
↑ "My encounter with Vigilante herdsmen in Ondo - Ajulo" . 22 July 2019. https://www.vanguardngr.com/2019/07/my-encounter-with-vigilante-herdsmen-in-ondo-ajulo/amp/ .
↑ "King Sunny Ade | Biography, Music, & Facts" . Encyclopedia Britannica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Chief (Dr.) Michael Ade Ojo, OON" . Eterna Plc (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-06-14. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Why Ondo Should Honour the Memory of Adefarati" . THISDAYLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-12-13. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Ondo former SSG turns movie producer" . The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-03-31. Archived from the original on 2021-06-28. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "The Poetics of Line" . africa.si.edu . Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Ilesanmi Adesida – Computer Scientist(?) Physicist(?) of the African Diaspora" . www.math.buffalo.edu . Retrieved 2021-06-28 .
↑ "I saw hell as Western region gov – Admiral Akin Aduwo" . The Sun Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-05-06. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Ondo govt. names university after Ex-Gov. Agagu | Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-02-04. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Akeredolu: Promoters of Oduduwa Republic are politicians who lost power" . TheCable (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-03-22. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Akintunde I. Akinwande – Computer Scientist of the African Diaspora" . www.math.buffalo.edu . Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Yemi Alade" . PAM – Pan African Music (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Gospel Singer Funmi Aragbaye Loses Husband" . Sahara Reporters . 2019-01-30. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Prominent Human Rights Activist Bamidele Aturu Dead At 49" . Sahara Reporters . 2014-07-09. Retrieved 2021-06-28 .
↑ Martins, Ameh (2019-11-08). "AKINYELURE, Patrick Ayo" . Biographical Legacy and Research Foundation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Reekado Banks" . SoundCloud (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Boroffice withdraws from race for Deputy Senate President" . The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-06-10. Archived from the original on 2021-06-28. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Yes, Third Term was my baby – Sen Ehinlanwo" . Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2012-04-19. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Omotola Jalade-Ekeinde: 10 things to know about 'Omosexy' " . CNN (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 17 January 2014. Retrieved 2021-06-28 .
↑ Olawale, Johnson (2017-05-31). "Bright ★ Star of YBNL Nation ★ Chinko Ekun" . Legit.ng – Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28 .
↑ "What South-West should do on herdsmen's migration —Olu Falae" . Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-09. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Biographical Legacy and Research Foundation" . https://blerf.org/index.php/biography/fasehun-frederick/ .
↑ "Gani Fawehinmi | Human rights campaigner | Obituary" . the Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2009-09-08. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Who be Jimoh Ibrahim? di Nigeria businessman wey billions of debt put for wahala" . BBC News Pidgin . https://www.bbc.com/pidgin/tori-55005985 .
↑ "Life and times of Prophet Temitope Balogun Joshua wey die at di age of 57" . BBC News Pidgin . https://www.bbc.com/pidgin/tori-57373898 .
↑ "The challenge facing the country today is poverty – Adetokunbo Kayode" . Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2011-11-01. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Nigeria, more divided along ethnic lines at 59 –Senator Kunlere" . Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-09-29. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "A Breakdown of Ayo Makun's Net Worth and The Success He's Had With AY Live" . Answers Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-01-22. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Former Ondo State governor Mimiko denies joining APC" . The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-06-04. Archived from the original on 2021-06-28. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Olajumoke: Philanthropist with human kindness" . Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-01-01. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Nigerian Military Rejects Amnesty International Report | Voice of America – English" . www.voanews.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Know Your Celebrities: 7 things you didn't know about actress Sola Sobowale" . Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-09-17. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Sowore explain why e show for court with 'traditionalist'" . BBC News Pidgin . https://www.bbc.com/pidgin/tori-56258213 .
↑ "Popular musician, Small Doctor, 3 others in police trouble for possession of firearm" . Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-04. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Waje Returns with Dauntless Vibe In Heart Seasons" . The Guardian Nigeria News – Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-05-01. Archived from the original on 2021-06-28. Retrieved 2021-06-28 .
↑ "Adaba 88.9 FM" . Adaba 88.9 FM .
↑ "Sunshine 96.5 FM Alalaye for Android - APK Download" . APKPure.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-07 .
↑ "Over 16,000 sign petition demanding Tinubu's probe" . Breez 91.9 FM . 28 August 2020. Archived from the original on 26 December 2021. Retrieved 11 September 2022 .
↑ "Crest 87.7 FM ...always at its peak" . crest877fm.com . Archived from the original on 2022-01-25. Retrieved 2022-09-11 .
↑ "About us – EKI 100.9 FM" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-12-05. Retrieved 2022-04-07 .
↑ "Empire FM Radio 104.5 On Line" . Radio.org.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-07 .
↑ "National Broadcasting Commission Applauds FUTA Radio" . The Federal University Of TEchnology Akure . Retrieved 2022-04-07 .
↑ "Home" . thehopenewspapers.com .
↑ "KAFTAN TV" . m.startimestv.com . Archived from the original on 2022-04-16. Retrieved 2022-04-07 .
↑ 84.0 84.1 "Ondo Election: 20 things to know about South-west state" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-10-09. Retrieved 2022-04-07 .
↑ "Orange Fm 94.5 || Urban FM Station || News || Music || Entertainment" . Orange 94.5 Fm . Archived from the original on 2022-09-27. Retrieved 2022-09-11 .
↑ "ONDO STATE RADIOVSION CORPORATION || NATION'S STAR STATION" . Ondo State Radiovision Corporation . Archived from the original on 2022-09-03. Retrieved 2022-09-11 .
↑ "positive" . radionigeriafm.com .
↑ "Tears all over moviedom for Mama remdel of life" . The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2016-05-21. Archived from the original on 2022-04-07. Retrieved 2022-04-07 .
↑ Precision. "Adedowole Named Pioneer General Manager Of RUGIPO FM | Precision" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-04-07 .
Àwọn ìtàkùn-ìtọ́kasí
Àdàkọ:Nigeria states Àdàkọ:Authority control Àdàkọ:Portal bar
Ìtọ́kasí