Ìdànrè, ìlú tí a mọ̀ sí Ufe Oke tẹ́lẹ̀, jẹ́ ìlú ìtàn ní ìpínlẹ̀ Ondo, olú-ìlú Idanre ni Idanre gẹ́gẹ́ bí orúkọ rẹ̀. Ìlú yìí wà ní scenic Idanre Hill tí ó sì tún jẹ́ ẹwà àti àṣà tí ó ṣe fojú rí láwùjọ,[1] tí ó sì ń wú àwọn arìnrìn-àjò lórí.[2][3][4][5]
Ìlú yìí tó ìwọ̀n 20km ti apá Gúsù sí ìlà-oòrùn olú-ìlú yìí, Akure, ó sì tún ní ìwọ̀n ilẹ̀ tó tó bíi 1,914 km2 (739 sq mi)àti ọ̀pọ̀ èrò tó tó 129,024 nígbà kíka ènìyàn ní ọdún 2006.[6] Kóòdù ìfìwéránṣẹ́ àgbègbè náà ni 340.[7] Idanre jẹ́ ìlú tí ó ní kòkó jù ní orílè-èdè Nàìjíríà.[8][9][10] Idanre ni ìlú tí a tí ń sọ èdè Yorùbá dáadáa (ó sún mọ́ èdè ìjímìjí Ondo) ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn ló ṣiṣẹ́ àgbè àti Iṣẹ́ òkòwò.
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ Ogunfolakan, Adisa (November 2012). "Report of geo-archaeological survey of Ufe-Oke (Oke-Idanre), Idanre, Ondo State, Nigeria". Quaternary International 279-280: 357–358. doi:10.1016/j.quaint.2012.08.1080. ISSN 1040-6182. http://dx.doi.org/10.1016/j.quaint.2012.08.1080.
- ↑ "Idanre Hills: Tourists haven on its knees", Daily Independent, 13 July 2012, archived from the original on 4 March 2016, retrieved 5 November 2017
- ↑ Oke Idanre (Idanre Hill) - UNESCO World Heritage Centre
- ↑ Frost, Darrel R. (2015). "Amietophrynus perreti (Schiøtz, 1963)". Amphibian Species of the World: an Online Reference. Version 6.0. American Museum of Natural History. Retrieved 24 October 2015.
- ↑ Onadeko, Abiodun B.; Rödel, Mark-Oliver; Liedtke, H. Christoph; Barej, Michael (2014). "The rediscovery of Perret's toad, Amietophrynus perreti (Schiøtz, 1963) after more than 40 years, with comments on the species' phylogenetic placement and conservation status". Zoosystematics and Evolution 90 (2): 113–119. doi:10.3897/zse.90.8234.
- ↑ "Idanre Hills, Ondo State". PacfNigeria. Archived from the original on 2014-10-31. Retrieved 2014-10-31.
- ↑ "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on 7 October 2009. Retrieved 20 October 2009.
- ↑ Frank H. Columbus (2001). Politics and Economics of Africa. 2. University of Virginia (Nova Science). ISBN 978-1-59-03327-88. https://books.google.com/books?id=I5RWAAAAYAAJ.
- ↑ Africa Today. 33. Afro Media. 1997. p. 42. https://books.google.com/books?id=vE0EAQAAIAAJ&q=Idanre+cocoa+largest+farming+nigeria.
- ↑ Ibrahim Apekhade Yusuf (Lagos); Damisi Ojo (Akure); Ernest Nwokolo (Abeokuta); Adesoji Adeniyi (Osogbo) (April 14, 2013). "Cocoa: Once upon a cash crop". The Nation. http://thenationonlineng.net/cocoa-once-upon-a-cash-crop/.