Li Na lo gba ife eye yi lodun to koja, sugbon ko kopa ninu idije yi lodun yi nitoripe o feyinti kuro ninu ise idije tenis ni 19 September 2014.
Serena Williams lo gba ife-eye na lodun yi, o bori Maria Sharapova ni ipari pelu ayo, 6–3, 7–6(7–5), lati gba ife-eye Open Australia kefa re ati ife-eye Grand Slam 19k enikan lakopo.[1][2]
Awon asayan
Draw
Ìtumọ̀
Finals
Top half
Section 1
Section 2
Section 3
Section 4
Bottom half
Section 5
Section 6
Section 7
Section 8
Itokasi