Bẹ̀lárùs, (pípè /bɛləˈruːs/ ( listen) bel-ə-ROOS; Bẹ̀l. Беларусь, Rọ́síà: Беларусь or Белоруссия, Belorussia see Etymology), lonibise bi Orile-ede Olominira ile Bẹ̀lárùs, je orile-ede ayikanule ni Apailaorun Europa,[4] to ni bode bi owo-ago pelu Rosia ni ariwailaorun, Ukrein ni guusu, Poland ni iwoorun, ati Lithuania ati Latvia si ariwaiwoorun. Oluilu re ni Minsk; awon ilu re pataki miran tun ni Brest, Grodno (Hrodna), Gomel (Homiel), Mogilev (Mahilyow) ati Vitebsk (Viciebsk). Idalogorun ogoji 207,600 square kilometres (80,200 sq mi) re lo je igbo aginju,[5] be sini apa okowo re to tobijulo ni ise agbe ati ise elero.
Itokasi