Republic of Latvia
Latvijas Republika
|
---|
|
|
|
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ | Riga |
---|
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Latvian |
---|
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 62.1% Latvians 26.9% Russians 3.3% Belarusians 2.2% Ukrainians 5.5% others[1] |
---|
Orúkọ aráàlú | Latvian |
---|
Ìjọba | Parliamentary republic |
---|
|
| Egils Levits |
---|
| Arturs Krišjānis Kariņš |
---|
| Ināra Mūrniece |
---|
|
Independence |
---|
|
| November 18, 1918 |
---|
| January 26, 1921 |
---|
| August 5, 1940 |
---|
| July 10, 1941 |
---|
| 1944 |
---|
| May 4, 1990 |
---|
| September 6, 1991 |
---|
|
Ìtóbi |
---|
• Total | 64,589 km2 (24,938 sq mi) (124th) |
---|
• Omi (%) | 1.57% (1,014 km2) |
---|
Alábùgbé |
---|
• 2016 estimate | ▼ 1,953,200 (148rd) |
---|
• 2011 ppl census | 2,067,887 [2] |
---|
• Ìdìmọ́ra | 34.3/km2 (88.8/sq mi) (166th) |
---|
GDP (PPP) | 2009 estimate |
---|
• Total | $32.234 billion[3] |
---|
• Per capita | $14,254[3] |
---|
GDP (nominal) | 2009 estimate |
---|
• Total | $26.247 billion[3] |
---|
• Per capita | $11,607[3] |
---|
Gini (2003) | 37.7 medium |
---|
HDI (2008) | ▲ 0.866 Error: Invalid HDI value · 48th |
---|
Owóníná | Euro (EUR) |
---|
Ibi àkókò | UTC+2 (EET) |
---|
| UTC+3 (EEST) |
---|
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
---|
Àmì tẹlifóònù | +371 |
---|
ISO 3166 code | LV |
---|
Internet TLD | .lv |
---|
1 Latvia is de jure continuous with its declaration November 18, 1918. |
Látfíà (Àdàkọ:Lang-lv), lonibise bi Orile-ede Olominira ile Látfíà (Àdàkọ:Lang-lv) je orile-ede ni agbegbe Baltiki ni Apaariwa Europe. O ni bode ni ariwa mo Estonia (343 km), ni guusu mo Lithuania (588 km), ni ilaorun mo Rosia (276 km), ati ni guusuilaorun mo Belarus (141 km).[4] Niwaju Omi-okun Baltiki ni iwoorun ni Swidin wa. Agbegbe Látfíà borile to to 64,589 km2 (24,938 sq mi) o si ni ojuoju tutu kakiri odun.
Itokasi