Orílẹ̀òmìnira ilẹ̀ Austríà Republic of Austria
[ Republik Österreich] error: {{lang}}: text has italic markup (help)
|
---|
|
|
|
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ | Vienna |
---|
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | German |
---|
Lílò regional languages | Slovene, Croatian, and Hungarian |
---|
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2001) | 91.1% Austrians, 8.9% foreigners - 4% former Yugoslavs, 1.6% Turks, 2.4% others and unspecified[1] |
---|
Orúkọ aráàlú | Austrian |
---|
Ìjọba | Federal Parliamentary republic |
---|
|
| Alexander Van der Bellen |
---|
| Karl Nehammer (ÖVP) |
---|
| Wolfgang Sobotka (ÖVP) |
---|
|
Independence |
---|
|
| 27 July 1955 (Duchy: 1156, Austrian Empire: 1804, First Austrian Republic: 1918–1938, Second Republic since 1945) |
---|
|
Ìtóbi |
---|
• Total | 83,855 km2 (32,377 sq mi) (115th) |
---|
• Omi (%) | 1.7 |
---|
Alábùgbé |
---|
• 2020 estimate | 8,935,112[2] (93rd) |
---|
• 2021 census | 8,932,664 |
---|
• Ìdìmọ́ra | 106/km2 (274.5/sq mi) (78th) |
---|
GDP (PPP) | 2018 estimate |
---|
• Total | $461.432 billion[3] |
---|
• Per capita | $51,936[3] |
---|
GDP (nominal) | 2019 estimate |
---|
• Total | $446.315 billion[3] |
---|
• Per capita | $50,277[3] |
---|
Gini (2020) | 27 [4] Error: Invalid Gini value |
---|
HDI (18) | ▼ 0.922[5] Error: Invalid HDI value · 18th |
---|
Owóníná | Euro (€) ² (EUR) |
---|
Ibi àkókò | UTC+01 (CET) |
---|
| UTC+02 (CEST) |
---|
Ojúọ̀nà ọkọ́ | ọ̀tún |
---|
Àmì tẹlifóònù | 43 |
---|
ISO 3166 code | AT |
---|
Internet TLD | .at ³ |
---|
|
Austríà (i /ˈɒustriə/ tabi /ˈɔːstriə/; [ˈøːstəˌʁaɪç] ( listen)), lonibise bi Orileominira ile Austria (German: Republik Österreich), je orile-ede atimo ile to ni awon eniyan bi egbegberun 8.8[2] to wa ni Aringbongan Yuropu. O ni bode mo Orileominira Tseki ati Jemani ni ariawa, Slofakia ati Hungari ni ilaorun, Slofenia ati Italia ni gusu, ati Switsalandi ati Likstenstein ni iwoorun. Gbogbo agbegbe ile Austríà je 83,855 square kilometres (32,377 sq mi) be sini ojuojo ibe je onitutu ati alpini. Ori ile Austríà je oloke gan nitori pe awon Alpi po nibe; 32% ibe nikan ni won wa ni abe 500 metres (1,640 ft), be sin oke re togajulo je 3,798 metres (12,461 feet).[6] Opo awon iyeolubugbe unso ede Jemani,[7] to tun je ede onibise orile-ede ohun.[8] Awon ede ibile onibise miran tun ni ede Kroatia, Hungari ati Slofenia.[6]
Austríà loni ni ibere re lati igba iran-oba Habsburg gegebi ara Obaluaye Romu Mimoy ti Orile-ede awon Ara Jemani; Austria di ikan ninu awon alagbara ninla ile Yuropu. Ni 1867, Ileobaluaye Austria je sisodi Austria-Hungary.
Obaluaye awon iran Habsburg (Austro-Hungarian) daru ni 1918 leyin opin Ogun Agbaye 1k, nigba Austria lo Austria Ara Jemani bi oruko („Deutschösterreich”, todi „Österreich”) lati ba se isokan po mo Jemani sugbon Adehun Saint Germain lodi si eyi. Igba Oselu Austria Akoko je didasile ni 1919. Ni igba Anschluss 1938, Austríà je bibolori latowo Jemani awon Nasi.[9] Eyi je be titi di opin Ogun Agbaye 2k ni 1945, leyin ti Jemani awon Nasi je bibori ogun latowo awon Ore eyi lo da oselu pada si Austríà. Ni 1955, Adehun Orile-ede Ara Austria satun-dasile Austria gegebi orile-ede alaselorile, lati fopin si ibolori. Ni odun yi kanna, Ileasofin Austria da Ifilole Aisojusaju to filole pe Igba Oselu Austria Keji yio di alaisojusaju titi lailai.
Loni, Austríà je oseluarailu asoju onileasofin to ni awon ipinle mesan.[6][10] Oluilu ati ilu re totobijulo, pelu iyeolubugbe to ju egbegberun 1.6, ni Vienna.[6][11] Austríà je ikan ninu awon orile-ede to lolajulo lagbaye, pelu IO oloruko ti enikookan to je $43,723 (idiye 2010). Orile-ede ohun ti sedagbasoke ona igbe giga, be sini ni 2010 o je onipo 25k lagbaye fun Atoka Idagbasoke Omoniyan re. Austríà ti je omo egbe Awon Orile-ede Asokan lati 1955,[12] o sora po mo Isokan Ara Yuropu ni 1995,[6] be sini o je ikan larin awon ti won da OECD sile.[13] Austríà tun fowobowe Ifenuko Schengen ni 1995,[14] o si gba owonina Yuropu, euro, ni 1999.
Itokasi