Muhammad Garba jẹ́ oníṣẹ́ ìròyìn Nàìjíríà ,[1] àti òṣèlú láti ìpínlẹ̀ Kano tí ó jẹ́ Kọmísọ́nà fún ìkéde.[2] àti ẹgbẹ́ kọmití International Federation of Journalists. [3]
A bí Muhammad ní Ọjọ́ Kejìlẹ́lógún oṣù kọkànlá ọdún 1965 ní agbẹ̀gbẹ̀ Yakasi, Kano Principal tí of Ipinle Kano. Ó lọ sí ilé-ìwé àkọ́bẹ̀rẹ̀ kofa Nassarawa àti Teachers college ní Sumaila níbi tí ó ti gba àmì ẹyẹ kí ó tó tẹ̀síwájú ní Yunifásítì Báyéró, Kano.[4][5]