Abdullahi Umar Ganduje, OFR tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1945 (25 December 1945) jẹ́ olóṣèlú àti Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kánò lọ́wọ́lọ́wọ́ láti ọdún 2015.[1] Kí ó tó di Gómìnà, òun ni igbákejì Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kano, lọ́dún 1999 sí 2003 àti 2011 sí 2015.
Àwọn Ìtọ́kasí