Although the Colombian Constitution does not specify the Spanish as official language in all its territory, the native languages (approximately 75 dialects) are also official in their own territories.
The official Colombian time, (horalegal.sic.gov.co) is controlled and coordinated by the state agency "Superintendencia de Industria y Comercio".[5]
Nibi odun 10,000 kJ, awon awujo ode ati akoeran wa nitosi ii ti Bogotá wa loni (ni "El Abra" ati "Tequendama") ti won sowo pelu ara won ati awon awujo miran ni Afonifoji Odo Magdalena Valley.[13] Bere ni egberundun akoko kJ, awon adipo awon omo Amerindia sedagbasoke sistemu oloselu to n je "cacicazgo" pelu opo agba bi piramidi, eyun latoke wa sisale ti awon olori re unje "cacique". Ninu Kolombia awon asa meji pelu sistemu cacicazgo lilojujulo ni awon Tayrona ni Agbegbe Karibeani, ati awon Muiska nibi awon ileoke layika Bogotá, awon mejeji ti won je ti ebi ede Chibcha. Awon Muiska ni won je gbigba bi awon ti won ni sistemu oloselu adagbasoke julo ni Guuusu Amerika leyin awon Inka.[14]
Awon oluwakiri ara Spein gunle si etiodo guusu Karibeani ni 1499 pelu Rodrigo de Bastidas bi olori won. Christopher Columbus gan na wa oko oju omi koja legbe Karibeani ni 1502. Ni 1508, Vasco Nuñez de Balboa bere sini se ijabori awon agbegbe Urabá. Ni 1513, ohun ni ara Europe akoko to de Okun Pasifiki, eyi to pe ni Mar del Sur ("Omi-okun Guusu"), nipa bayi o si ona fun awon ara Spein yioku lati lo si Peru ati Tsile. Gbogbo agbegbe yi ni awon eya bi awon Chibchan ati awon Carib, awon yi ti awon ara Spein bori diedie boya pelu ijagun tabi nipa ibarepo, Nigbakana, awon arun ti awon ara Europe mu wa pelu won, bi sopanna, ati ija ibori ati ipalemo eya eniyan to n sele, fa diedie ki awon olugbe abinibi ibe o idin pupo.[15] Ni orundun 16th awon ara Europe bere si ni mu awon eru wa lati Afrika.
Igbominira lowo Spein
Leyin ibori Kolombia lowo awon ara Spein ati igba pipe imunisin lowo won, opo egbe arinkankan lodide lati gba idawa tabi ilominira patapata agbegbe orile-ede. Opo ni awon wonyi ni awon ara Spein fi jagidijagan ko nile, be sini awon miran ninu won ko ni agbara to lati mu iyipada wa. Egbe arinkankan fun ilominira to gbeyin bere arin 1810, leyin igba ti Saint Domingue (Haiti loni) gba ilominira ni 1804. Eyi fu itileyin gidi fun awon to solori ijidide ni Kolombia, eyun Simón Bolívar ati Francisco de Paula Santander. Bolívar di Aare akoko orile-ede Kolombia alominira leyin ijabori ni ijaogun Boyacá, leyin ti Bolívar fipo yi sile, Santander to je igbakeji re di Aare ikeji orile-ede Kolombia. Ijidide yi pari layorisirere ni 1819, nigbati Ibasorun ile Grenada Tuntun bo si owo Orile-ede Olominira Kolombia ti a sese dasile ngbana bi isokan Ekuador, Kolombia ati Venezuela. Panama nigbana je apa ile Kolombia.
Kolombia je pipin si awon 32 ipinpa 32 ati agbegbe oluilu kan, ti won mu bi ipinpa kan (Bogotá na tun je oluilu fun ipinpa Cundinamarca). Awon ipinpa na tun je pinpinlabe si awon munisipal, ikokan won to ni ibujoko munisipal, bakanna awon munisipal tun je pipinsabe si corregimientos. Ipinpa kokan ni ijoba ibile pelu gomina ati ile-igbimo asofin ti won n je didiboyan tara si igba odun merin. Munispal kookan ni baale ati igbimo, be sini corregimiento kookan ni corregidor, tabi olori ibile.
Lapapo mo oluilu, awon ilu miran na tun wa ti pe ni agbegbe, nitori ini pataki ti won ni. Awon wonyi ni Barranquilla, Cartagena, Santa Marta, Cúcuta, Popayán, Bucaramanga, Tunja, Turbo, Buenaventura ati Tumaco. Awon apaipin ni ipinabe ibile amojuto, nibi ti awon ilu ni awon olugbe to tobi ti won si wa nitosi ara won (fun apere ni Antioquia ati Cundinamarca). Nibi to ba je pe aon olugbe kere sugbon won ni isoro abo (fun apere Amazonas, Vaupés ati Vichada), ipin amojuto pataki je lilo, bi "apaipin corregimientos", to je adapo ilu ati corregimiento.
E te klik sori apaipin kan lori maapu lati losi ayoka re.
Awon oro okere ile Kolombia je latowo Aare ile Kolombia won si unje kikoso latowo Alakoso Oro Okere. Colombia ni awon iranlose diplomati ni gbogbo orile-ede be sini o je sisoju ninu awon agbajo alakopapupo ni awon ibudo yi:
↑"Decreto 2153 de 1992"(PDF). Presidencia de la República de Colombia. Archived(PDF) from the original on 2011-05-14. Retrieved 2008-10-13.Unknown parameter |cite= ignored (help); Unknown parameter |idiom= ignored (help)
↑The Geographer Office of the Geographer Bureau of Intelligence and Research (1985-04-15). "Brazil-Colombia boundary"(PDF). International Boundary Study. Archived from the original(PDF) on 2006-09-16. Retrieved 2008-01-05.
↑CIA (2007-12-13). "Ecuador". World Fact Book. Archived from the original on 2007-06-12. Retrieved 2008-01-05.
↑Van der Hammen, T. and Correal, G. 1978: "Prehistoric man on the Sabana de Bogotá: data for an ecological prehistory"; Paleography, Paleoclimatology, Paleoecology 25:179–190
↑Broadbent, Sylvia 1965: Los Chibchas: organización socio-política. Série Latinoamericana 5. Bogotá: Facultad de Sociología, Universidad Nacional de Colombia