Orile-ede Olómìnira Nagorno-Karabakh (NKR)[2] (Arméníà: Լեռնային Ղարաբաղի Հանրապետություն Lernayin Gharabaghi Hanrapetut’yun, or Artsakh Republic (Arméníà: Արցախի Հանրապետություն Arts'akhi Hanrapetut’yun)[2] je de facto orile-ede olominira to budo si agbegbe Nagorno-Karabakh (tabi agbegbe Artsakh) ni Guusu Kaukasu.
Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.