Jaafar Jaafar jẹ́ akọ̀ròyìn ilẹ̀ Nigerian ọ́ jé ọmọ bíbí ìlú Kano state ó sì jẹ́ Olùdásílẹ̀ Daily Nigerian, ilé iṣẹ atẹ̀wéjáde orí ẹ̀rọ ayélujára èyí tí ó ṣe àgbéjáde àgbékúrú fídíò tó takọ Gómìnà ìpínlẹ̀ Kano, Abdullahi Umar Ganduje fún gbígba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ $5 million ní October 2018.[2][3][4]
Àwọn ìtọ́kasí
- ↑ "Presidency caught showcasing Kwankwaso's projects as Jonathan's achievement in North-West | Premium Times Nigeria". 25 November 2014.
- ↑ "REVEALED: The face of Nigerian governor caught on tape receiving $5m bribe". Daily Nigerian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 10 October 2018. Archived from the original on 20 September 2020. Retrieved 1 February 2021.
- ↑ "EXCLUSIVE VIDEO: Kano governor, Abdullahi Ganduje, caught receiving bribe". Daily Nigerian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 14 October 2018. Archived from the original on 10 March 2021. Retrieved 1 February 2021.
- ↑ "EXCLUSIVE: Nigerian governor caught on video receiving $5m bribes". Daily Nigerian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 8 October 2018. Archived from the original on 26 September 2021. Retrieved 1 February 2021.