Anthony Afọlábí Adegbola (ọjọ́ìbí 24 February 1929) jẹ Òjògbón ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí sáyẹnsì Ẹranko atí Ààrẹ ilé ẹ̀kọ́ gígá tí Nàìjíríà tèlé.[1] Ní odún 1993, ọ jẹ Alàkóso tí Nigerian Academy of Science láti rọ́pò Òjògbón Akpanoluo Ikpong Ikpong Ette.[2]
Anthony Afolabi Adegbola |
---|
Ọjọ́ìbí | 24 Oṣù Kejì 1929 (1929-02-24) (ọmọ ọdún 95) Owerri, Ìpínlẹ̀ Imo |
---|
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
---|
Iṣẹ́ |
- educator
- microbiologist
- researcher
|
---|
Àwọn ìtọkásí