*Bharat Ganarajya, that is, the Republic of India in Hindi,[4] written in the Devanāgarī script. See also other official names ‡ This is the figure as per the United Nations though the Indian government lists the total area as 3,287,260 square kilometres.[10]
Gẹ́gẹ́ bíi ilẹ̀ Ọ̀làjú Àfonífojì Indus jẹ́ ibí tó ní ìdàgbàsókè púpọ̀, abẹ́orílẹ̀ Índíà jẹ́ ibi àwọn ènìyàn mọ̀ fún ọlá àti àṣà rẹ̀ káàkiri ayé.[13] Esin nla merin, Hinduism, Buddhism, Jainism ati Sikhism ni won bere latibe, nigbati Zoroastrianism, Esin Ju, Esin Kristi ati Imale de sibe ni egberundun akoko IO (CE) won si kopa ninu bi orisirisi asa agbegbe na seri. Diedie o je fifamora latowo British East India Company lati ibere orundun ikejidinlogun, o si di ile amusin Ile-oba Isodokan lati arin orundun ikandinlogun, India di orile-ede alominira ni 1947 leyin akitiyan fun isominira to se pataki fun isatako alaise jagidijagan kakiri.[15]
Awon ibugbe apata Igba Okuta pelu awon iyaworan ni Bhimbetka rock shelters ni Madhya Pradesh ni eri igbe eniyan pipejulo ni India. Awon ibudo akoko ti a mo bere ni odun to ju 9,000 seyin lo, diedie o si dagba soke si Indus Valley Civilisation,[20] ti ojo ori re to odun 3400 BCE ni apaiwoorun India. Eyi je titele pelu Vedic period, to se ipilese Esin Hindu ati awon asa miran igba ibere awujo India, o si pari ni awon odun 500 BCE. Lati bi 550 BCE, opolopo awon ile-oba alominira ati orile-ede olominira ti a mo bi Mahajanapadas je didasile kakiri ibe.[21]
Leyin awon iborile lati Arin Asia larin orundun 10th ati 12th, opo Ariwa India ni won bo si abe ijoba Delhi Sultanate ati leyin eyi sabe Ileobaluaye Mughal. Labe isejoba Akbar the Great, India gbadun idagbasoke asa ati okowo pupo ati irepo esin.[25][26] Awon obaluaye Mughal diedie fe ile won si pupo lati dori apa nla abeorile. Sibesibe, ni Ariwa-Apailaorun India, alagbara to joba ibe ni ileoba Ahom ti Assam, gege bi ikan ninu awon ileoba ti won lodi si ijobalenilori Mughal. Ihalemo ninla akoko si agbara ijoba Mughal wa latodo oba HinduRajput kan Maha Rana Pratap ti Mewar ni orundun 16th ati leyin eyi latodo orile-ede Hindu kan to n je adapapo Maratha, to joba lori opo India ni arin orundun 18th.[27]
Lati orundun 16th, awon alagbara ara Europe bi Portugal, Hollandi, Fransi, ati Iparapo Ileoba se idasile ibudo owo (trading posts) be sini leyin eyi won lo anfani ti awon ija abele ibe fa wa lati sedasile awon ibiamusin nibe. Nigba to fi di 1856, opo India ti bo sabe idari British East India Company.[28] Odun kan leyin eyi, igbogundi kakiri awon eyo ologun olodi ijoba ati awon ileoba, ti a mo bi Ogun Ilominira Akoko India tabi Sepoy Mutiny, koju idari ile-ise yi gidigidi sugbon ko yori si rere. Nitori aidurorege, India bo si abe isejoba taara Oba Alade Britani.
Ni ojo 15 osu kejo 1947, India gba ilominira kuro lowo isejoba Britani, sugbon nigba kanna awon agbegbe ogunlogo Musulum je pipinniya lati da orile-ede otooto Pakistan.[30] Ni ojo 26 osi kinni 1950, India di orile-ede olominira be sini ilana ibagbepo tuntun je gbigbe jade.[31]
Ilana-Ibagbepo ile India, to je ilana-ibagbepo togunjulo ati to kunrerejulo ti orile-ede alominira lagbaye, je gbigba bi ofin ni 26 January 1950.[34]Akokosoilana-ibagbepo yi setumo India gege bi orile-ede olominiratoseluaralusovereign, sosialisti, ti araaye.[35] India ni ileasofin oniyewumeji to n sise bi sistemu onileasofin iru Westminster. Iru ijoba re je jijuwe pe o je bi 'quasi-federal' pelu gbongan to lagbara ati awon ipinle ti won ko lagbara,[36] sugbon o ti di apapo diedie lati opin awon odun 1990 nitori awon iyipada oloselu, olokowo ati alawujo.[37]
Aare ile India ni olori orile-ede[38] to je didiboyan latowo igbimo onidiboyan[39] fun igba odun marun kan.[40][41]Alakoso Agba ni olori ijoba, ohun lo si segbese opo agbara alase.[38] Gege bi yiyan latowo Aare,[42]Alakoso Agba je titileyin latowo egbe oloselu tabi ifowosowopo oloselu to ni ogunlogo awon ijoko ni ile kekere Ileasofin.[38] Apa ijoba apase ni Aare, Igbakeji Aare, ati Igbimo awon Alakoso (Kabinet ni igbimo apase re) ti olori re je Alakoso Agba. Alakoso yiowu to ni ipo gbodo je ikan ninu awon omo ile ileasofin. Ninu sistemu onileasofin ti India, apase wa labe asofin, nibi ti Alakoso Agba ati Igbimo re wa labe ile kekere.[43]
Asofin ile India ni Ileasofin oniyewumeji, to ni ile oke ti o n je Rajya Sabha (Igbimo awon Ipinle) ati ile kekere to n je Lok Sabha (Ile awon Eniyan).[44] Rajya Sabha, agbarajo aiyese, ni 245 omo egbe ti won wa nibe fun odun marun.[45] Opo won je didiboyan taara latowo awon asofin ipinle ati agbegbe gege bi iye awon eniyan won.[45]
↑"Total Area of India"(PDF). Country Studies, India. Library of Congress – Federal Research Division. December 2004. Retrieved 2007-09-03. The country’s exact size is subject to debate because some borders are disputed. The Indian government lists the total area as 3,287,260 square kilometres and the total land area as 3,060,500 square kilometres; the United Nations lists the total area as 3,287,263 square kilometres and total land area as 2,973,190 square kilometres.
↑"Constituent Assembly of India — Volume XII". Constituent Assembly of India: Debates. parliamentofindia.nic.in, National Informatics Centre. 1950-01-24. Retrieved 2007-06-29. The composition consisting of the words and music known as Jana Gana Mana is the National Anthem of India, subject to such alterations in the words as the Government may authorise as occasion arises; and the song Vande Mataram, which has played a historic part in the struggle for Indian freedom, shall be honoured equally with Jana Gana Mana and shall have equal status with it.
↑ 12.012.1"India", Oxford English Dictionary, second edition, 2100a.d. Oxford University Press.
↑Echeverri-Gent, John (2002). "Politics in India's Decentred Polity". In Ayres, Alyssa; Oldenburg, Philip. Quickening the Pace of Change. India Briefing. London: M.E. Sharpe. ISBN076560812X. at pp. 19–20; Sinha, Aseema (2004). "The Changing Political Economy of Federalism in India". India Review3 (1): 25. doi:10.1080/14736480490443085. at pp. 25–33.
↑ 38.038.138.2Sharma, Ram (1950). "Cabinet Government in India". Parliamentary Affairs4 (1): 116–126.
↑"Election of President". The Constitution Of India. Constitution Society. Retrieved 2 September 2007. The President shall be elected by the members of an electoral college.
↑Gledhill, Alan (1964). The Republic of India: The Development of Its Laws and Constitution (2nd ed.). Stevens and Sons. p. 112.
↑"Tenure of President's office". The Constitution Of India. Constitution Society. Retrieved 2 September 2007. The President shall hold office for a term of five years from the date on which he enters upon his office.
↑"Appointment of Prime Minister and Council of Ministers". The Constitution Of India. Constitution Society. Retrieved 2 September 2007. The Prime Minister shall be appointed by the President and the other Ministers shall be appointed by the President on the advice of the Prime Minister.