Ipinle Delta jẹ́ ọ̀kanIlára àwọn Ìpínlẹ̀ nií riílẹ̀-èdèNaijiria. Ìpínlẹ̀ Delta wà ní apá Gúúsù Nàìjíríà. Adá Ìpínlẹ̀ ìíkalẹ̀ ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n, oṣù keẹjọ ọdún 1991lábé ìjọba Gen. Ibrahim Babangida [1]. Olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Delta ni Asaba, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ìlú Warri ni àárín ajé Ìpínlẹ̀ Delta. Àwọn èyà tí ópọ̀ jùlọ í Ìpinlè Delta ni Igbo, Urhobo, Isoko, Ijaw, Itsekiri [2]. Ìpinlè Delta ní Ìjọba Àgbègbè Ìbílè márùndílọ́gbọ̀n (25) [3] Gómìnà Ifeanyi Okowa ní gómìnà Ìpínlẹ̀ Delta lọ́wọ́.
Awon Ìjoba Agbegbe Ìbílè ti Delta
- Ariwa Aniocha
- Guusu Aniocha
- Bomadi
- Burutu
- Guusu Ethiope
- Ila-oorun Ethiope
- Ariwa Ila-oorun Ika
- Guusu Ika
- Ariwa Isoko
- Guusu Isoko
- Ila-oorun Ndokwa
- ìwọ̀ oòrùn Ndokwa
- Okpe
- Ariwa Oshimili
- Guusu Oshimili
- Patani
- Sapele
- Udu
- Ariwa Ughelli
- Guusu Ughelli
- Ukwuani
- Uvwie
- Ariwa Warri
- Guusu Warri
- Guusu ìwọ̀ oòrùn Warri
Àwọn olókìkí ènìyàn láti Delta
Àwọn Ìtọ́kasí