Ìgbà Ààrẹ Umaru Musa Yar'Adua bere ni 29 May, 2007 leyin ayeye ibura gege bi Aare orile-ede Naijiria ketala. Ki Yar'Adua o to di Aare o ti koko je Gomina Ipinle Katsina lati 1999 de 2007. Ninu idiboyan to waye ni April 21, 2007 Yar'Adua lo bori pelu ibo 24.6 legbegberun to je 70% awon ibo didi si 6.6 legbegberun ti Muhammadu Buhari to je olutako re julo. Sibesibe awon olutako oniselu pe idiboyan ohun ni ojoro won si bere fun ifagile re.
Itokasi