Àwọn ọmọ Nàìjíríà Amẹ́ríkà (Nigerian Americans) ní àwọn ará Amẹ́ríkà tí wọ́n ní ìbátan mọ́ ará Nàìjíríà. Ìdíye tí American Community Survey ṣe ní ọdún 2016 sọ pé àwọn ará ìlẹ̀ Amẹ́ríkà tí wọ́n pe ara wọn ní ọmọ Nàìjíríà tó 380,785.[3] Nínú wọn, àwọn 277,027 ni wọ́n bí ní Nàìjíríà.[4]
Nigeria is both the most populous country in Africa—190.8 million as of 2018[5]—and the African country of origin with the most migrants in the United States, as of 2013.[6]