Àwọn ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn ni "awo eto ipile ati ominira ti gbogbo awon omo eniyan leto si."[1] Awon olugbowo ero yi un tenumo pe gbogbo awon eniyan ni awon ajemonu nitoripe won je omo eniyan.[2]
Nitorie awon eto omoniyan je gbigba bi ti eyi to je alagbalaaye ati bakanna. Iru awon ajemonu bayi le wa gege bi awon asa awon iwuwa eniyan gangan, gege bi asa iwa tito tabi awon eto eda ti o ni idi pataki, tabi gege bi awon eto olofin boya ninu orile-ede tabi ninu ofin kariaye.[3]
Sibesibe, ko si ikoenu lori kini ohu pato to je tabi ti ko je eto omoniyan lona kankan, be si ni ero awon eto omoniyan bi afoyemo ti je ohun ijiyan ati igbeyewo ninu imo oye.