Wọ́n ṣe ìfilọ́lẹ̀ Ilé-ìgbìmọ̀ àwọn aṣòfin kẹwàá lọ́jọ́ kẹtàlá oṣù kẹfà ọdún 2023. Àpapọ̀ gbogbo wọn jẹ́ 360.
Lọ́jọ́ tí ṣe ìfilọ́lẹ̀ yìí, ẹgbẹ́-ọ̀ṣèlú All Progressive Congress ní ìjókòó ọmọ ẹgbẹ́ aṣojú-ṣòfin 162, Peoples Democratic Party ní 102, Labour Party ní 34, bẹ́ẹ̀ ni ẹgbẹ́-òṣèlú NNPP ní ìjókòó 18. APGA ní ìjókòó mẹ́rin; African Democratic Congress (ADC) àti Social Democratic Party ní ìjókòó méjì méjì; bẹ́ẹ̀ ni ẹgbẹ́ the YPP ní jíjókòó kan péré[1][2]. Lọ́jọ́ náà, ayé ìjókòó ẹni méjì ṣófo nítorí pé wọn kò tíì ṣètò ìdìbò wọn tán. Àjọ Independent National Electoral Commission, INEC sì kéde pé wọn yóò ṣètò láti ṣe àtúndì-ìbò ní àwọn ẹkùn-ìdìbò méjèèjì tí ayé wọn ṣì ṣófo
Ádárì
Àwọn olùdarí=
Orúkọ ipò
|
Ẹgbẹ́-òṣèlú
|
Onípò
|
Ipinlẹ̀
|
Ẹkùn-ìdìbò
|
Láti
|
Speaker of the House
|
APC
|
Abbas, TajudeenTajudeen Abbas[3]
|
Kaduna
|
Zaria Federal Constituency
|
Kaduna I
|
2023-06-13 13 June 2023
|
Deputy Speaker of the House
|
APC
|
Benjamin Kalu[4]
|
Abia
|
Bende Federal Constituency
|
2023
|
2023-06-13 13 June 2023
|
Olùdarí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tó pọ̀ jùlọ
Olùdarí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ tó kéré
Orúkọ ipò
|
Ẹgbẹ́-òṣèlú
|
Ọmọ ẹgbẹ́
|
Ìpínlẹ̀
|
Ẹkùn ìdìbò
|
Láti
|
House Minority Leader
|
PDP
|
Kingsley Chinda[7]
|
Rivers
|
Obio/Akpor Federal Constituency
|
2023-07-4 4 July 2023
|
Deputy House Minority Leader
|
NNPP
|
Ali Madaki
|
Kano
|
Dala Federal Constituency
|
2023-07-4 4 July 2023
|
House Minority Whip
|
PDP
|
Ali Isa[8]
|
Gombe
|
Balanga/ Billiri constituency
|
2023-07-4 4 July 2023
|
Deputy House Minority Whip
|
LP
|
George Ozodinobi
|
Anambra
|
Dunukofia Njikoka Anaocha Federal Constituency
|
2023-07-4 4 July 2023
|
Àwọn ìtọ́kasí