Onírúurú ayẹyẹ ni wọ́n máa ń ṣe ní orílẹ̀-èdè Tunisia lọ́dọọdún, èyí tí a pín wọ́n pẹ̀lú oṣù tí wọ́n máa ń ṣe wọ́n nínú àtòjọ ìsàlẹ̀ yìí...
Àtòjọ àwọn ọdún tí wọ́n ń ṣe ní Tunisia pẹ̀lú oṣù wọn
Oṣù kejì
- Ọdún ohun èlò ìkọrin làgbàáyé. Tí ó ń sọ nípa àwọn àṣà àwọn tí wọ́n ń bẹ ní àríwá ilẹ̀ Áfíríkà – Tunis
Oṣù kẹta
Oṣù kẹrin
Oṣù karùn-ún
- Ọdún ìrékọjá – El-Ghriba Synagogue, Djerba. (oṣù kẹrin tàbí oṣù karùn-ún)
- Ọdún Jerid – Nefta àti káàkiri gbogbo àyíká ìlú
- Ọdún orin . Orin àlùjó àti tàkasúfèé – Sfax
Oṣù kẹfà
Oṣù keje
Oṣù kẹjọ
Oṣù kẹsàn-án
Oṣù kẹwàá sí oṣù Kejìlá
- Ọdún fíìmù ti Carthage (Journées cinématographiques de Carthage, JCC) - Tunis
- Ọdún ìkórè Date – Kebili (oṣù kọkànlá)
- Ọdún Oases káríayé – Tozeur (Oṣù Kọkànlá)
- Ọdún káríayé ti Sahara. Ijó, orin, àti eré orí ìtàgé - Douz (November–December)
- Sfax International Mediterranean Film Festival - Sfax (oṣù Kejìlá)
Àwọn Ìtọ́kasí
- ↑ "Carthage Music Festival" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 20 February 2016.