Èyí ni àtòjọ àwọn olórin tó gbajúmọ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Àwọn tí wọ́n jẹ́ ìlú mọ̀ọ́ká nìkan ni a kó jọ sí abẹ́ ààtò yí. Ẹ lè wo àtòjọ ìpín àwọn orin orílẹ̀ èdè náà ní ẹ̀ka 'Nigerian musical groups'.
0-9
A
B
C
- CDQ-olórin Ráàpù àti Olùkọrin
- Chidinma - olórin Pọ́ọ̀pù
- Chike
- Celestine Ukwu - olórin Highlife
D
E
- Frank Edwards - olórin gospel
- Omotola Jalade Ekeinde - olórin R&B àti Pọ́ọ̀pù
- eLDee - olórin Ráàpù, Olùkọrin ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
- Emma Nyra - olórin R&B
- Emmy Gee - olórin Ráàpù
- Alhaji Dauda Epo-Àkàrà - Àwúrèbe
F
- Falz - olórin Ráàpù àti Olùkọrin
- Majek Fashek - olórin R&B àti Olùkọrinàti Olùkọrin
- Faze - olórin R&B
- Flavour N'abania - olórin Pọ́ọ̀pù àti Highlife
G
- Tonye Garrick - olórin R&B àti Olùkọrin
- Adekunle Gold - olórin àti Olùkọrin
- Ruby Gyang
H
- Harrysong - olórin àti Olùkọrin
- Humblesmith -olórin Afro àti Pọ́ọ̀pù
I
J
K
L
M
- Mayorkun
- M.I - olórin Ráàpù
- M Trill -olórin Ráàpù
- J. Martins - olórin tí ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
- May7ven
- Prince Nico Mbarga
- Maud Meyer - olórin jáàsì
- Mike Ejeagha - olórin Highlife
- Mo'Cheddah -olórin Pọ́ọ̀pù
- Mode 9 - olórin Ráàpù
- Cynthia Morgan - olórin Pọ́ọ̀pù àti dacehall
- Mr 2Kay
- Mr Raw
- Muma Gee - olórin Pọ́ọ̀pù àti Olùkọrin
- Muna - olórin Ráàpù
- Muraina Oyelami
N
O
P
- Patoranking - olórin régè àti dancehall
- Pepenazi - olórin Ráàpù, Pọ́ọ̀pù, Olùkọrin ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
- Peruzzi
- Shina Peters - olórin Afro-Jùjú
- Phyno - olórin Ráàpù ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
- Praiz - olórin R&B àti Olùkọrin
R
S
T
- Tekno Miles - olórin Afro-Pọ́ọ̀pùolórin R&B àti Olùkọrin
- Terry G - olórin R&B, Olùkọrin ó sì tún ń gbé àwọn olórin mìíràn jáde
- Timaya - olórin régè
- Tiwa Savage - olórin R&B àti Olùkọrin
- Tony Tetuila-olórin R&B àti Olùkọrin
U
- Sir Victor Uwaifo - olórin highlife
W
Y
- YCEE - olórin Ráàpù
- Yemi Blaq
- Yung6ix - olórin Ráàpù
Z
Ẹ̀ tún lè wo
Àwọn ìtọ́ka sí