Up North jẹ́ fíìmù àgbéléwò tí ó jáde láti ọwọ́ Anakle Films and Inkblot Productions [2]ní ọdún 2018 ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí diTope Oshin[3] ṣe olùdarí rẹ̀. Naz Onuzo and Bunmi Ajakaiye ló kọ ire náà látàrí itan tí Editi Effiong kọ.[4] Ní ìlú Bauchi ni wọ́n ya iṣẹ́ náà, pẹ̀lú yíya ọ̀sẹ̀ kan ní ìlú Èkó Lagos.[5]
Àwọn akópa
Àwọn Ìtọ́kasí