Udom Gabriel Emmanuel (ojoibi 11 July 1966) ni gomina Ipinle Akwa Ibom ni Naijiria, o wa lori aga lati 29 May 2015 leyin igbatowe leyin idibo April 2015 labe egbe oloselu People's Democratic Party. Won tun tundiboyan sipo gomina ni ojo 29k osu karun odun 2019.[1]
Àwọn Ìtọ́kasí