Theophilus Yakubu Danjuma GCON FSS psc (ojoibi 9 December 1938) je ogagun to ti feyinti, oloselu ati onisowo ara Naijiria lati eya Jukun. O je Oga Omose Agbogun Naijiria lati July 1975 de October 1979. O si tun je Alakoso Oro Abo labe ijoba Olusegun Obasanjo.[1] Danjuma ni alaga ile-ise South Atlantic Petroleum (SAPETRO).[2]
Itokasi
Àwọn Ọ̀gá àwọn Ọmọṣẹ́ Jagunjagun Nàìjíríà (COAS) |
---|
|