Saint Martin (Faransé: Saint-Martin; Duki: Sint Maarten) je erekusu amooru ni ariwailaorun Karibeani, bi 300 km (186 miles) ilaorun orile-ede Puerto Rico. Erekusu yi to je 87 km2 je pipin ni 60/40 larin Fransi (53 km2)[1] ati Netherlands Antilles (34 km2)[2]; ohun ni erekusu to kerejulo ti awon eniyan n gbe si ninu okun ti o je pipin larin awon orile-ede meji, eyi je be lati odun 1648.
Itokasi