Pierre Eugène Jean Pflimlin (ìpè Faransé: [pjɛʁ flimlɛ̃][1]; 5 February 1907 - 27 June 2000) je ara Fransi oloselu oseluarailu elesin Kristi to di Alakoso Agba ni Igba Oselu Kerin fun ose die ni 1958, ko to di pe Charles de Gaulle ropo re ni May 1958.[2]
Itokasi