Philip Seymour Hoffman |
---|
Hoffman in October 2011 |
Ọjọ́ìbí | 23 Oṣù Keje 1967 (1967-07-23) (ọmọ ọdún 57) Fairport, New York, U.S. |
---|
Iṣẹ́ | Actor, director |
---|
Ìgbà iṣẹ́ | 1991–present |
---|
Alábàálòpọ̀ | Mimi O'Donnell (1999–present) |
---|
Philip Seymour Hoffman (ojoibi July 23, 1967) je osere ati oludari filmu ara Amerika to gba Ẹ̀bùn Akádẹ́mì fún Òṣeré Okùnrin Dídárajùlọ. Hoffman bere isere lori telifisan ni 1991, lodun to tele o bere sini kopa ninu filmu. O bere sini gbajumo diedie fun isere itinleyin re ninu awon filmu bi Scent of a Woman (1992), Twister (1996), Boogie Nights (1997), The Big Lebowski (1998), Magnolia (1999), The Talented Mr. Ripley (1999), Almost Famous (2000), 25th Hour (2002), Cold Mountain (2003), Along Came Polly (2004), ati Mission: Impossible III (2006).
Itokasi